Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 296 Bibel’ iwe aiyeraiye! Lyrics

Hymn 296 Bibel’ iwe aiyeraiye! Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Bibel’ iwe aiyeraiye!
Tani le r’ idi re?
Tani le so idide re?
Tani le m’ opin re?

2 Asiri Olodumare;
Iko Oba orun;
Ida t’o pa oro iku;
Aworan Olorun.

3 Okan ni O larin opo
Iwe aiye ’gbani,
Iwo l’o s’ ona igbala
Di mimo f’ araiye.

4 Isura ti Metalokan,
Oba nla t’o gunwa;
Jo, tumo ara re fun mi,
Ki ’m ye siyemeji.

5 Ki ’m’ si o pelu adura,
Ki ’m’ k’ eko ninu re;
Iwo Iwe Aiyeraiye
F’ ife Jesu han mi. Amin.

Exit mobile version