Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 294 Iwe kan wa ti kika re Lyrics

Hymn 294 Iwe kan wa ti kika re Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Iwe kan wa ti kika re,
Ko soro fun enia,
Ogbon ti awon t’o ka nfe,
Ni okan ti o mo.

2 Ise gbogbo t’ Olorun se.
L’ oke, n’ ile; n’nu wa;
Nwon j’ okan ninu iwe na,
Lati f’ Olorun han.

3 Imole osupa l’ oke,
Lat’ odo orun ni:
Be l’ ogo Ijo Olorun,
T’ odo Olorun wa.

4 Iwo ti O je ki a ri,
Ohun t’ o dara yi:
Fun wa l’ okan lati wa O,
K’a ri O nibi gbogbo. Amin.

Exit mobile version