Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 284 E fi ogo fun Baba Lyrics

Hymn 284 E fi ogo fun Baba Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 E fi ogo fun Baba,
Nipa Eniti a wa;
O ngbo adura ewe,
O nf’ eti si orin won.

2 E fi ogo fun Omo,
Kristi, ’Wo ni Oba wa;
E wa, e korin s’ oke,
S’ Odagutan elese.

3 Ogo fun Emi Mimo,
Bi ojo Pentikosti;
Ru aiya awon ewe,
F’ orin mimo s’ ete won.

4 Ogo ni l’ oke orun,
Fun Eni Metalokan;
Nitori ihin rere,
Ati ife Olorun. Amin.

Exit mobile version