Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 278 Si O, Olutunu orun Lyrics

Hymn 278 Si O, Olutunu orun Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Si O, Olutunu orun,
Fun ore at’ agbara Re,
A nko Alleluya.

2 Si O, ife enit’ o wa
Ninu majemu Olorun,
A nko Alleluya.

3 Si O, Ohun Eniti npe
Asako kuro n’nu ese,
A nko Alleluya.

4 Si O, agbara Eniti
O new ni mo, t’ o nwo ni san,
A nko Alleluia.

5 Si O, ododo Eniti
Gbogbo ’leri Re je tiwa,
A nko Alleluia.

6 Si O, Oluko at’ Ore,
Amona wa toto d’ opin,
A nko Alleluya.

7 Si O, Eniti Kristi ran,
Ade on gbongbo ebun Re,
A nko Alleluia.

8 Si O, Enit’ o je okan
Pelu Baba ati Omo,
A nko Alleluya. Amin.

Exit mobile version