Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 270 Adaba orun, sokale Lyrics

Hymn 270 Adaba orun, sokale Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Adaba orun, sokale,
Gbe wa lo l’ apa iye Re;
Ki o sig be wa ga soke,
Ju gbogbo ohun aiye lo.

2 Awa iba le ri ite
Olodumare Baba wa,
Olugbala joko nibe,
O gunwa l’ awo bi tiwa.

3 Egbe mimo duro yi ka,
Ite, Agbara wole fun,
Olorun han ninu ara,
O si tan ogo yi won ka.

4 Oluwa, akoko wo ni
Emi o de bugbe loke?
T’ emi o ma ba won wole,
Kim ma sin O, ki mma korin? Amin.

Exit mobile version