Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 265 ‘Gbani t’ Olorun sokale Lyrics

Hymn 265 ‘Gbani t’ Olorun sokale Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 ‘Gbani t’ Olorun sokale,
O wa ni ibinu;
Ara sin san niwaju Re,
Okunkun on ina.

2 Nigbati’ o wa nigba keji,
O wa ninu ife;
Emi Re si ntu ni lara,
B’ afefe owuro.

3 Ina Sinai ijo kini,
T’ owo re mbu soke,
Sokale jeje bi ade,
Si ori gbogbo won.

4 Bi ohun eru na ti dun,
L’eti Israeli,
Ti nwon si gbo iro ipe,
To m’ ohun angeli gbon.

5 Be gege nigbat’ Emi wa
Ba le awon Tire,
Iro kan si ti orun wa,
Iro iji lile.

6 O nkun Ijo Jesu, o nkun
Aiye ese yika;
L’okan alaigboran nikan
Ni aye ko si fun.

7 Wa, Ogbo, Ife, at’ Ipa,
Mu ki eti wa si;
K’a ma so akoko wa nu;
Ki ‘fe Re le gba wa. Amin.

Exit mobile version