Hymn 222 Oluwa ji loto Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 Oluwa ji loto,
Olugbala dide,
O f’ agbara Re han.
L’ or’ orun apadi:
N’ iberu nla; awon eso
Subu lule, nwon si daku.
2 Wo, egbe angeli
Pade l’ ajo kikun;
Lati gbo ase Re,
Ati lati juba:
Nwon f’ ayo wa, nwon s info lo,
Lati orun si boji na.
3 Nwon tun fo lo s’ orun,
Nwon mu’ hin ayo lo;
Gbo iro orin won,
Bi nwon si t info lo.
Orin won ni, Jesu t’ o ku,
Ti ji dide; o ji loni.
4 Enyin t’ a ra pada,
E gberin ayo na;
Ran iro re kiri,
Si gbogbo agbaiye.
E ho f’ ayo. Jesu t’ o ku,
T ji dide: ki y’o ku mo.
5 Kabiyesi! Jesu!
T’ o f’ eje Re gba wa;
Ki iyin Re kale,
Iwo t’ o ji dide:
A ba O ji, a si joba,
Pelu Re lai; l’ oke orun. Amin.
