Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 192 Iwo elese, Emi nfi anu pe Lyrics

Hymn 192 Iwo elese, Emi nfi anu pe Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Iwo elese, Emi nfi anu pe
Okan re t’o ti yigbi ninu ese;
Mase ba Emi ja, ma pe titi mo,
Ebe Olorun re le pari loni.

2 Omo Ijoba, ma s’m eru ese mo;
Gb’ ebun Emi Mimo ati itunu:
Ma bi Emi ninu, Oluko re ni, –
K’a ba le se Olugbala re logo.

3 Tempili d’ ibaje, ewa re d’ ile;
Ina pepe Olorun fere ku tan,
Bi a fi ife da, O si le tun ran :
Mase pa’na Emi, Oluwa mbo wa. Amin.

Exit mobile version