Hymn 179 Baba alanu t’o fe wa Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 Baba alanu t’o fe wa,
Mo gb’ okan mi si O;
Ipa Re t’ o po l’ o gba wa;
Awa nkorin si O.
2 Tire papa l’ awa fe se,
Gb’ okan wa fun ebo;
O da wa, o sit un wa bi,
A f’ ara wa fun O.
3 Emi Mimo, wa sodo mi,
F’ ife Oluwa han;
Fun mi k’ emi k’ o le ma rin,
N’ ife Oluwa mi. Amin.
