Hymn 166 Kristi t’ agbelebu l’ orin wa Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 Kristi t’ agbelebu l’ orin wa,
Ijinle t’ awa nso;
O j’ egan loju awon ju,
Were lowo Griki.
2 Sugbon okan t’ Olorun ko
F’ ayo gba oro na;
Nwon ri ogbon, ipa, ife,
T’ o han n’ Oluwa won.
3 Adun oruko Re yiye
Mu ’soji s’ okan won;
Aigbagbo l’ohun t’ o ba ni je,
Si ebi at’ iku.
4 Lai j’ Olorun t’ or’ ofe ka
Bi owara ojo;
Lasan l’ Apollos funrugbin,
Paul si le gbin lasan. Amin.
