Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 151 Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re Lyrics

Hymn 151 Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re,
S’ oro Alafia;
Gbogbo ipa mi y’o dalu
Lati yin ore Re.

2 Fi iyonu pe mi l’ omo,
K’ o si dariji mi;
Ohun na yio dunmo mi,
B’ iro orin orun.

3 Ibikibi t’ o to mi si,
L’ emi o f’ ayo lo;
Tayotayo l’ emi o si
Dapo m’ awon oku.

4 ’Gba eru ebi ba koja,
Eru mi ko si mo;
Owo t’ o fun ’dariji ka,
Y’o pin ade iye. Amin.

Exit mobile version