Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 120 Oluwa y’o tip e to Lyrics

Hymn 120 Oluwa y’o tip e to Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Oluwa y’o tip e to
Ti ’Wo o tun pada
Are fere mu wa tan,
Bi a ti nwona Re;
Oluwa, y’o ti pe to
Ta o ma reti Re ?
Opo ni ko gbagbo mo
P ’Wo o tun pada.

2 Oluwa y’o tip e to
Ti ’Wo o kesi wa ?
Ti awa, ti nreti Re
Yio ri O l’ ayo ?
Ji, wundia ti o sun,
Lo kede bibo Re
Ki gbogbo awon t’ o sun
Le mo pe O mbo wa.

3 Dide, tan fitila re,
Gbe ewu mimo wo,
Mura lati pade Re,
’Tori On fere de.
Oluwa, y’o tip e to
Ti ’Wo o tun pada ?
Ma je ki are mu wa
Tit’ a o fi ri O. Amin.

Exit mobile version