Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 111 Larin ijo Kristian Lyrics

Hymn 111 Larin ijo Kristian Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Larin ijo Kristian
Je k’ ife wa yika;
Awon t’ is’ ajumo- jogun
Ti y’o jo gba ’bukun.

2 K’ ilara, om’ esu,
Jina si odo wa;
Kia won ti ngbe t’ Oluwa,
Wa n’ ife t’ o daju.

3 Bayi n’ Ijo t’ ihin
Y’ o farawe t’ oke,
Nibi isan ife gbe wa
Ife l’ okan gbogbo. Amin.

Exit mobile version