Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 100 Alakoso ti orun Lyrics

Hymn 100 Alakoso ti orun Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Alakoso ti orun,
Alanu at’ Ologbon;
Igba mi mbe lowo Re,
Opin gbogbo l’ase Re.

2 Ase Re l’o da aiye
Ati ibi mi pelu;
Obi, ile, on igba;
Nipa Re ni gbogbo won.

3 Igb’ aisan, on ilera,
Igba ise on oro;
Igba ’danwo, ibinu,
Igba ’segun, iranwo.

4 Igba iridi Esu
Igba ’to ’fe Jesu wo,
Nwon o wa, nwon o si lo,
B’ Ore wa orun ti fe.

5 Iwo Olore- ofe,
’Wo ni mo f’emi mi fun,
Emi jewo ife Re,
Emi teriba fun O. Amin.

Exit mobile version