Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 559 E gbe ohun ayo at’ iyin ga Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 559 E gbe ohun ayo at’ iyin ga Lyrics

Hymn 559 E gbe ohun ayo at’ iyin ga Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 559 E gbe ohun ayo at’ iyin ga Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 E gbe ohun ayo at’ iyin ga, Alle| luya!
Orin ogo Oba nla l’awon ti a rapada|
y’o ma ko: Alle| luya! Alle| luya!

2 Awon egbe ako| rin orun,
Nwon o gberin na yi| ka orun;
Alle| luya! Alle| luya!

3 Awon ti nrin gbefe kiri ni Pa| radise,
Awon eni ’bukun ni, nwon o ma ko| rin
Wipe,
Alle| luya! Alle| luya!

4 Awon ’rawo ti ntan | mole won,
Ati gbogbo awon egbe irawo, da ohun
Won | lu wipe,
Alle| luya! Alle| luya!

5 Enyin sanma t’o nwo si lo, at’enyin | efufu,
Enyin ara t’o nsan wa, | enyin manamana
t’o| nko mana;
E fi a| yo gberin, Alle| luya!

6 Enyin omi, at’ igbi okun, enyin ojo, a| t’ otutu,
Enyin ojo dida| ra gbogbo,
Enyin igboro at’ igbo, e| gberin na,
Alle| luya!

7 Enyin oniruru eiye, e korin iyin Ele| da
nyin pe,
Alle| luyah! Alle| luya!

8 Enyin eranko igbe, e d’o| hun nyin lu
E si korin iyin Ele| da wipe,
Alle| luya! Alle| luya!

9 Je k’awon oke k’o| bu s’ayo
Alle| luya!
K’awon petele si | gberin na,
Alle| luya!

10 Enyin ogbun omi okun, e | ko wipe,
Alle| luya!
Enyin ile gbigbe, e, da| hun wipe,
Alle| luya!

11 Olorun t’O| da aiye, ni k’a| f’orin yin;
Alle| luya! Alle| luya!

12 Eyi l’orin ti Olo| run wa fe,
Alle| luya!
Eyi l’orin ti Krist tika| lare fe
Alle| luya!

13 Nitorina, tokantokan l’ao| fi korin,
Alle| luya!
Awon omode wewewe y’o gba orin
Alle| luya!

14 Ki gbogbo enia | ki o ko
Alleluya si| Olorun;
Alleluya ti| ti aiye,
Fun Omo on E| mi Mimo.

15 Ogo ni f’Olo| go Meta
Alle| luya! Alle| luya! Alle| luya! Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 558 Wo, owon Olurapada Lyrics
Next: Hymn 560 E wole f’Oba, Ologo julo Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 98 Olorun Betel, eniti Lyrics
  • Hymn 111 Larin ijo Kristian Lyrics
  • Hymn 188 Olorun, Baba mi, ’Wo npe Lyrics
  • Hymn 290 Bawo ni awon ewe wa Lyrics
  • Hymn 79 Ojo ayo nlanla na de Lyrics
  • Hymn 55 Oluwa mbo; aiye o mi Lyrics
  • Hymn 564 L’oko Jesu, gbogbo ekun yio wole Lyrics
  • Hymn 509 O s’ ohun t’o ti mi loju Lyrics
  • Hymn 25 Ojo ‘simi at’ ayo Lyrics
  • Hymn 496 Oluwa, k’ a ha w’ odo Re Lyrics
  • Hymn 337 Awa ko orin ife Re Lyrics
  • Hymn 58 Yo, enyin onigbagbo Lyrics
  • Hymn 275 Emi Mimo ‘Dada orun Lyrics
  • Hymn 167 Ki se l’ainireti Lyrics
  • Hymn 235 Ojo ’mole l’eyi Lyrics
  • Hymn 115 E yo Jesu joba Lyrics
  • Hymn 118 Lat’ oke tutu Grinland Lyrics
  • Hymn 359 Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re Lyrics
  • Hymn 495 A o pade leti odo Lyrics
  • Hymn 294 Iwe kan wa ti kika re Lyrics
  • Hymn 16 Iwo Imole okan mi Lyrics
  • Hymn 478 Ona kan l’o ntoka sorun Lyrics
  • Hymn 221 Eyi l’ojo ajinde Lyrics
  • Hymn 124 Ilu t’ o dara po l’ aiye Lyrics
  • Hymn 402 Ojo nsure, o nkoja Lyrics
  • Hymn 182 Are mu o, aiye su o Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 129 Olorun, gbogbo araiye Lyrics
  • Hymn 26 Olusagutan eni re Lyrics
  • Hymn 270 Adaba orun, sokale Lyrics
  • Hymn 447 Duro, omo ogun Lyrics
  • Hymn 103 Kabiyesi ! Isun ’bukun Lyrics
  • Hymn 112 Gbo ! orin ti Jubeli Lyrics
  • Hymn 405 Tire l’ola Baba Lyrics
  • Hymn 292 Iwo Oro Olorun Lyrics
  • Hymn 491 Mase huwa ese Lyrics
  • Hymn 507 Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi Lyrics
  • Hymn 5 Wa s’odo mi, Oluwa mi Lyrics
  • Hymn 490 K’ awa to pari eko wa Lyrics
  • Hymn 393 Wa, ma sise Lyrics
  • Hymn 492 Olusagutan mi Lyrics
  • Hymn 557 Emi ’ba n’ egberun ahon Lyrics
  • Hymn 165 Si pepe Oluwa Lyrics
  • Hymn 272 Wa, Parakliti mimo Lyrics
  • Hymn 598 E korin s’Olorun wa Lyrics
  • Hymn 14 Ife Re da wa si loni Lyrics
  • Hymn 346 Alabukun ni fun ife Lyrics
  • Hymn 514 Gbat’ a kun fun banuje Lyrics
  • Hymn 412 Mura, elese, lati gbon Lyrics
  • Hymn 584 Enit’ O la ’ju afoju Lyrics
  • Hymn 586 Ma koja mi, Olugbala Lyrics
  • Hymn 215 Isimi awon mimo Lyrics
  • Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics
  • Hymn 234 Jesu, wa sarin wa Lyrics
  • Hymn 196 Hosanna s’Omo Dafidi Lyrics
  • Hymn 385 Gbekele Olorun re Lyrics
  • Hymn 148 Baba wa orun npe Lyrics
  • Hymn 362 Larin ewu at’ osi Lyrics
  • Hymn 489 Jesu, a w’ odo Re Lyrics
  • Hymn 513 Gb’ ohun t’o t’ orun wa ti wi Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version